Home

News

Prophetess Tola Ara - Isoji | mp3 Download

Prophetess Tola Ara – Isoji | mp3 Download

No Comments Lyrics Music News

Prophetess Tola Ara – Isoji | mp3 Download

Prophetess Tola Ara - Isoji

Prophetess Tola Ara – Isoji | mp3 Download  ~ Prophetess Tola Ara Set to drop another debut single titled “ISOJI” after her previous hot trending Single ARA SAN which God has used to touch many lives, ISOJI is a heavenly Revival song which was sent through Prophetess Tola Ara, Recorded at Grace Studio and Packaged by Obeylee

FOLLOW THE LYRICS

E fun ipe naa kikan
Ipe ihinrereee,
Oni jakeee jadooo
Leti gbogbooo eda

RESP/CHRS…………….
Odun idaaa sileee ti deee
Pada elese pada aaaaa
Odun idaaa sileee ti deee
Pada elese padaaa.

VOCAL: mo fe k’ola jesu han Lara miiiiiii,

mo fe k’ola jesu han Lara mi. 2x.
*bi mo ti nlo bi mo ti mbo laarin aiyeee.
bi mo ti nlo bi mo ti mbo laarin aiyeee
mo fe k’ola jesu han lara miii,
mo fe k’ola jesu han lara miii.

L/SOLO: Ore bi jesu, kosi laiye yii
Ohun nikan n’ore o titooo

PERCUSSION…………….
Ore aiye yii le ko wa sile,
Sugbon jesu ko je e
Gbagbe miii
CALL:… ko Jeee gbagbe mi o
RESP:…haaaa ko je gbagbe mi
CALL:… ore o ti to.
RESP:…haaaa ko je gbagbe mi
Halleluyah
Sugbon jesu ko je
gbagbe mi.

DOWNLOAD NOW

Follow NetunezFacebook | Instagram | Twitter

 

share this

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Tags: , , ,