Home

Music

CCC KOK CHOIR WAKATI YI ~ DELE BLACKO FEAT SEYI SOLAGBADE

  • Release date: December 9, 2022
  • Label: CCC KOK CHOIR
  • Catalog #: 1

CCC KOK CHOIR WAKATI YI ~ DELE BLACKO FEAT SEYI SOLAGBADE

  1. 1

    WAKATI YI CCC KOK CHOIR ~ DELE BLACKO FEAT SEYI SOLAGBADE

    Download track Lyrics

    WAKATI YI –CCC KOK CHOIR ~ DELE BLACKO FEAT SEYI SOLAGBADE

    WAKATI YI LYRICS
    yago lola Mariya gariyeh.......

    Efori bale foba awon oba, foba awon oba......

    (Verse 1)
    Ara San niju asi were loba ko so ni

    Olorun Celestial dakun maje Kawa ro fo.

    Orun tin polongo ara re , ninu ijomimo o

    Pe jomimo ni yio we e aye mo.

    ila orun iwo orun gusu ariwa

    Etara sa sa emu ade oba re wa .

    Kigbogbo aye leri pe woni olorun.

    Imole mo si awon keferi .

    Egan yio do go, ogun esu yio do fo,

    imo ota yo ditemole niwaju wa.

    Hook. 👇

    Baba a (baba ba ba ba )

    ni wa a kati yi (ni wa kaaati yi)

    Gbese owo ore ga a (gbese gbese gbese gbese e)

    Ki gbogbo aye le mo (kan le e mo)

    Peyin leran wa ni se e.

    Verse 2)
    Ya allah Ka dau kaka Kankakee

    da alhuma duniya

    da mutani zasu sani che wa

    Yesu Kadai ne nai ubangiji..

    ummm yin arare logo Olorun awon angeli...

    jekaraye mope Jesu nikan loba...

    iwoniapata ti ijomimo durole

    Olorun Eledumare...

    yara gbawa oo...

    Baba a a

    (dakun gba mi)

    ni waakaa ti yi (asiko to araye Tira lo,abo awa dowo re o heeee)

    Gbese owo re ga a

    Ki gbogbo aye le mo (peyin leran wa ni se o eheeee.)

    Pe yin le ran wa ni se

    La San la San heeeeeeee.

    Lasan laye mi gbe ogun

    Wakati na de taye owa riri

    (Yahgo lola Mariya gariyeh yeh gbogbo aye yio wole le fun )

    Labe agbara mimo (loruko jesu yi o)

    Jesu.

Follow Netunez: Facebook | Instagram | Twitter

share this