AJIJOOLA – ONA IYE
AJIJOOLA – ONA IYE
-
1
ONA IYE AJIJOOLA
Download track LyricsONA IYE –AJIJOOLA
Mo ti mo ona iye yi na , ona ara ologo ni
Mo ti mo ona iye yi na Baba je kin sin o do pin
Araye e tan imole so na okukun aye yi, awon ti ofe ni Baba yan
Awon to yan ni Baba se lo go.
Ijo ti yio we aye yi mo leyi
Ema ku ta so go Olorun.
CHORUS
Ero ya wa ooo (2ce)
Wa gbo hun ti Olujo mimo nso
Teti ko gbohun t,olujo mimo nwi.
Emi ti wa lo na iye yi n
Afi ye mi pe ona ologo ni, ogo to ntan to pa okukun re
Imole ayeraye ti ko lku lai lai
Afi fun mi pelu ore ofe, ogbe mi ga ju gbogbo elegan lo
Ona too ro lo na iye yi sibe odun jo yin lo
Si be o dun jo yin lo .
REPEAT CHORUS
Ee mi ti wa lo na Iye yi na, afi ye mi p'ona oologo ni
Ogo to ntan to pa okuku re Imole ayeraye ti I kole ku lai lai
Repeat till fade.