Bukunmi Babarinsa ft Harjovy – Gba Isakoso | mp3 Download
Bukunmi Babarinsa ft Harjovy – Gba Isakoso | mp3 Download, – Overview on Bukunmi Babarinsa a fast-rising gospel music artiste signed under KAMTV RECORDS Management, set to drop the most anticipated track titled Gba Isakoso “Take Control” featuring Harjovy the Worship machine, this song was originally composed by Mr. Babarinsa years before the birth of Bukunmi Babarinsa, Gba Isakoso is Executively Produced by Harjovy and also Produced, Mixed and Mastered by Mr Spectacular Eskeez at Codedtunes Studio, Lagos Nigeria for more Enquiries Contact KAMTV RECORDS HQ ON +447459132458 or on our social media platforms @kamtvchannel
Chai! Oya feel the lyrics small i beg…
Chants
Pipele,Pipele lo n pele o
Pipele,Pipele lo n pele o
Pipele,Pipele lo n pele ooo
Pipele,Pipele lo n pele o
Kaka k’ewe agbon de
Pipele lo n pele
Kaka k’oro iya aje,
O fi gbogbo omo re b’obirin
Kaka k’ewe agbon de
Pipele, Pipele lo n pele o
Ye, Oluorun o
Dide wa ran wa l’owo o
Gbo ohun ebe wa, ni Naijiria yi o
Olododo o si mo, won s’aye di je ki n je
Igunnugun yan ni je, Akala yan ni je, o lo o
Ye, Oluorun , Eledumare, wa ko wa yo
A n be o, Oluwa, dide ko gba Isakoso
Yi igba buburu pada si rere fun wa
Ounje to won, so won d’opo fun wa
Mekunnu n jiya, Eledumare wa ko wa yo
Rogbodiyan ile aye yi papoju, la se ke si o o
Lai si ese, ijiya o si o, Eledumare wa darijini
Pipele,Pipele lo n pele o e
Pipele,Pipele lo n pele o
Pipele,Pipele lo n pele si i, lojojumo o
Pipele,Pipele lo n pele o
Kaka k’ewe agbon de
Pipele lo n pele
Kaka k’oro iya aje, o fi gbogbo omo re b’obirin
Kaka k’ewe agbon de
Pipele, Pipele lo n pele o
[Lyrics] Bukunmi Babarinsa ft Harjovy – Gba Isakoso
Chants
Pipele, Pipele lo n pele o
Pipele, Pipele lo n pele o
Pipele, Pipele lo n pele ooo
Pipele, Pipele lo n pele o
Kaka k’ewe agbon de
Pipele lo n pele
Kaka k’oro iya aje,
O fi gbogbo omo re b’obirin
Kaka k’ewe agbon de
Pipele, Pipele lo n pele o
Ye, Oluorun o
Dide wa ran wa l’owo o
Gbo ohun ebe wa, ni Naijiria yi o
Olododo o si mo, won s’aye di je ki n je
Igunnugun yan ni je, Akala yan ni je, o lo o
Ye, Oluorun , Eledumare, wa ko wa yo
A n be o, Oluwa, dide ko gba Isakoso
Yi igba buburu pada si rere fun wa
Ounje to won, so won d’opo fun wa
Mekunnu n jiya, Eledumare wa ko wa yo
Rogbodiyan ile aye yi papoju, la se ke si o o
Lai si ese, ijiya o si o, Eledumare wa darijini
Pipele,Pipele lo n pele o e
Pipele,Pipele lo n pele o
Pipele,Pipele lo n pele si i, lojojumo o
Pipele,Pipele lo n pele o
Kaka k’ewe agbon de
Pipele lo n pele
Kaka k’oro iya aje, o fi gbogbo omo re b’obirin
Kaka k’ewe agbon de
Pipele, Pipele lo n pele o
Chants
Trumphet
L’aye ojosi, b’omo ba ka iwe mefa
Bi eni ka gbogbo iwe ni o o
Iwe kika jo’ju , laye ojosi, b’omo ba ka iwe mefa
Bi eni ka gbogbo iwe ni e e
Sugbon l’ode oni o, aye ti d’obiripo
Omo re Yunifasiti, o ri bi eni re je’le-osinmi
Omo ka gbogbo iwe tan
O wa se, wa se o, ko ma ri ‘se fi se
Ki l’anfaani Satifike t’a gba ta o ri ‘se fi se
Ki l’afaani ile iwe t’a lo, t’a jade ti a o ri’se
Ebe la be yin, eyin ijoba
E ba wa , w’ono abayo, tori
Owo to ba di’le, l’esu n ran ni’se, eyi l’adigunjale fi po o
Iwa ibaje lorisirisi, ojoojumo lo n gbile si
Ka maa pa’ra wa, bi eni p’eran
Ko ti le, jo wa l’ojumo
419 lorisirisi, iwa ibaje d’oun a mu s’oge
Awa n be o Eledua, Baba, ma se wo wa ni’ran
Tete je ki’joba re de, k’a se bere lori ase’bi
Ki’na Orun sokale wa o, ko jo gbogbo imo esu run
Ki iya to n je Olododo, ko le d’oun igbagbe o
Ko le d’oun igbagbe o
Ko le d’oun ari’pitan
Ko le d’oun igbagbe o
Ko le d’oun amu’pitan
Si’ju aanu re wo wa o
Edumare wa tun Naijiria yi se
Si’ju aanu re wo wa se
Edumare wa tun Naijiria yi se
Orileede yi n fe atunse
Edumare wa tun Naijiria yi se
A ti f’otito pamo, iro nikan la n pon o
Edumare wa tun Naijiria yi se
A f’oun to ye sile, ase’yi ti ko ye
Edumare wa tun Naijiria yi se
Ah! Oba Edumare dakun gba wa o
Edumare wa tun Naijiria yi se
Ninu rogbodiyan ile aye yi
Edumare wa tun Naijiria yi se
Omo ka iwe tan, e mo ri’se fi se
Edumare wa tun Naijiria yi se
Eni n s’ise da bi ole o
Edumare wa tun Naijiria yi se
Igbe ole loni, igbe ole lola
Edumare wa tun Naijiria yi se
419 lorisirisi
Edumare wa tun Naijiria yi se
Bee, ita’jesi’le l’o’lokanojokan
Edumare wa tun Naijiria yi se
A wa da bi agutan ti ko l’oluso o
Edumare wa tun Naijiria yi se
Ki iya to n je Olododo, k’o le d’oun igbagbe o
Ko le d’oun igbagbe o
Ko mo le d’oun ari’pitan
Ko le d’oun igbagbe o
Ko le d’oun amu’pitan
Si’ju aanu re Baba o
Edumare wa tun Naijiria yi se
Jowo dakun Baba si’ju aanu re wo wa
Edumare wa tun Naijiria yi se
Gbogbo wa n w’odo b’ose n gbe’gi Arere lo o
Edumare wa tun Naijiria yi se
Igba ti Odo n gba’rere lo o
Edumare wa tun Naijiria yi se
Ba wo ni, Ba wo ni, t’Araba yo se ri
Edumare wa tun Naijiria yi se
Ba wo l’eyin ola awon omo wa yo se ri
Edumare wa tun Naijiria yi se
Ebi ti so’po eniyan d’alarinkiri
Edumare wa tun Naijiria yi se
Won n se ”Bambi Allah” ki won to jeun
Edumare wa tun Naijiria yi se
Won n se ”Bambi Allah” e bun mi nitori Oloun Oba o
Edumare wa tun Naijiria yi se
Asita ibon n d’emi awon eyan l’egbodo o
Edumare wa tun Naijiria yi se
Awon agbesunmomi n fooro emi wa
Edumare wa tun Naijiria yi se
Let the killings stop! Let the violence cease!
Edumare wa tun Naijiria yi se
T’oba je t’ese, Baba darijini
Edumare wa tun Naijiria yi se
F’orjiwa dakun, s’aanu fun wa o
Edumare wa tun Naijiria yi se
T’oba je t’ese, Baba a be o
Edumare wa tun Naijiria yi se
Dee’reign – Ise Iyanu | mp3 Download. – Overview on Dee’reign who is also Known as Ogunmakinju Damilola Remilekun is set to drop the most anticipated Single titled “ISE IYANU”. This Great Song is inspired a few years back by God. I thank him for the Miraculous things he has done in my life since my tender age till this moment. with the Support of a MAN who God will continue to Bless His Handwork and His Entire Family. Special thanks to God for Mr. Alabama Georgia1 for the supervision of this wonderful project. Ise Iyanu is produced by Dejikeyz, Mixed, and Mastered by Ultradii.
DOTVOCALZ – JEHOVAH SABAOTH | mp3 Download | Overview on a Fast-rising gospel music act, Adebowale Olamidotun a.k.a Dotvocalz who has been in the industry for so many years and has organized various music concerts in different states and places such as Lagos, Ibadan, Ogbomoso, Osun, Ogun state and so on in the country Nigeria. Adebowale Olamidotun has featured many great gospel artistes in Nigeria. In anticipation of his forthcoming album, Dotvocalz is set to release a single out of his forthcoming album titled JEHOVAH SABAOTH which is produced by Menejazz and Mikkybass. JEHOVAH SABAOTH talks about how powerful our God is fighting our battles day in day out, the known battles and the unknown battles, this is the reason why this song is coming out to those who know the great impact of the Almighty God in their life in other to appreciate the Lord’s Kindness because God alone deserves our praises.
JEHOVAH SABAOTH is set to be released and premiered across various platforms online, on-air, and on various radio stations and also available on all streaming platforms on the 26th of September, 2020. To know more about the artiste Adebowale Olamidotun Dotvocalz kindly reach us through our social media handle IG @dotvocalz FB @Adebowale Dotvocalz Olamidotun TWITTER@DOTVOCALZ1
Overview on SEYIDIVA popularly known as Talabi Oluwaseyi Omotola, set to drop her most anticipated First Ever Hot Single Titled “HAPPY DAY ” Produced Mixed and Mastered by Eskeez Spectacular.
Seyidiva is a Hip-hop artist, songwriter, and a recording artist, who has been featured on many movie soundtracks such as Ariran, Oju Ade, Akere, Ewo ibi, House of Jagaban and many more… Listen, Enjoy, and share with love.
Nazarite Your Presence | mp3 Download – Nazarite releases his first worship singles titled “Your Presence” “Your Presence” emphasizes the irreplaceable need for God in our lives as well as the wonderful privilege we have through Christ to come into God’s presence lifting our holy hands in worship Nazarite had taken a break after his first two albums, while he studies at West Africa Theological Seminary for a Masters in Divinity. The TrueWorshippers Movements’ favorite released “Your Presence” as a tool for pure worship and spiritual reawakening. Your Presence is produced by Ayo Ephphatha