Jide Grace – EMIKO Lyrics
Jide Grace – EMIKO Lyrics
Si eni to l’ogo eeee
Eeeeeeee
Adapada fun, eni to logo, ibere owun gbogbo
Tolorun ba gbe ni ga debi tio ro
Awa ronu jinle wipe semi nan reee
Oke ti alagbara gun to mi ele
Lomo olorun gun to pada wa dupe
Tolorun ba gbe ni ga, debi tio ro
Awa ronu jinle wipe semi nan reee
Emi no reeeeee eeee eeee
Oke ti alagbara gun to mi ele
Lomo olorun gun to pada wa dupe
Adani waye tidani saye , emiko mo se
Kin sagba ra tabi mo mi lo fi yori
olowo olorun ninu emiko mo se
Ti nba wa sobe pe
Ti nba so pe ooo , emini mo se ooo
Iro mooopa
Eni tojumi lo omo si
Olowo olorun ninu emiko mo se
Ti ba so so pe oo, emi ni mose ooo iro mopa
Tin ba so pe emi ni mose, iro mo npa
Taleni feba o pin oh ninu ogo re oo olorun,
Kose ni le ba o fi iga gba gaaaaa aaa aaa
Them no fit to take ur place oba mi ti mo mo, ti mo mo, ti mo mo
Ibere ati opin alpha and omega aa aa aaaa
Oke t’alagbara gun to kan lese
Owun lemi omo re gun
Ti mo tun pada wa dupe ese
Adani waye tida ni saye , emiko mo se
Kin sagba ra tabi mo mi lo fi yori
Oni lati ni
olowo olorun ninu emiko mo se
Ema sobe mo
Ti nba so pe ooo , emini mose ooo
Iro mooopa
Olowo olorun ninu emiko mo se
Ti baso so pe oo, emini mose ooo iro mo npa
Bi ba se re to kole na awon ton ko se lasan ni o
Lasan ni ooo
Won o bi mi da pe
Agbara mi koo imo temo koo oo olorun mi lose
Gbona boba dosan madupe botun dasale masope
Gbope gbayin wa
Emi nikantan oo losore yi fun ooo gbogbo gba mama dupe
Halleluyah ni mo ma fi dupe
Hosannah ni mafi dupe
Adani waye salo se be
Agbara mi ko, imo temi ko oo, olorun lose